Pages:
Author

Topic: Yoruba language (Read 1054 times)

newbie
Activity: 15
Merit: 0
March 12, 2024, 03:40:03 PM
#34
Nje gbogbo wa le ran arawa lowo lati ma fun ra wa ni merit daradara. Ati wipe sale se afihan ibi to gbogbo wa tiwa,  tori wipe kale mo opportunity ta lagbara latise fun rawa.
newbie
Activity: 15
Merit: 0
March 02, 2024, 06:07:29 PM
#33
Inu mi lati wa larin yin nibi.
newbie
Activity: 17
Merit: 0
January 01, 2023, 04:10:08 PM
#32
E kaale nibi o
Se awa omo Yorùbá sii wa nibi abi atilo?
sr. member
Activity: 392
Merit: 262
Lohamor Family
December 20, 2022, 06:43:38 PM
#31
Ekale ni bi o,awon omo iya mi
Mi o mo pe ani ibi bayi ni ile yi
Baba Nla Mmpamegbu elenu pa bi ese da ibi ti ati le soro ni ede Yoruba.
Olorun lo ma gbo adura wa
Koni baje.
newbie
Activity: 44
Merit: 0
August 07, 2022, 02:23:32 PM
#30
Ede to dungbo leti ni ede yoruba to dun so lawujo, if anybody have interest in learning it I'm available to help them.
Cause I'm happy how my language is been speaking here.
sr. member
Activity: 980
Merit: 237
August 06, 2022, 10:21:50 AM
#29
I do not speak yoruba language but I had to learn some for easy community relations. Some of the word commonly used are;
• eloni - how many
•wa jewun - come and eat
•meji -2
•meta - 4
•ekaro - good morning
•eka sun - good afternoon
•odaro - goodnight

So many to say but these came out quickly.

newbie
Activity: 195
Merit: 0
August 05, 2022, 02:21:00 PM
#28
Mo ki yin gbo omo oduduwa oooo..., a daara ko gbogbo wa ooo.
newbie
Activity: 44
Merit: 0
August 05, 2022, 03:20:50 AM
#27
Inu mi dun lati darapo mo ipejopo yi, mode fe je ki gbogbo wa fowosopo lati ranrawa lowo,
member
Activity: 71
Merit: 22
May 01, 2022, 10:52:58 AM
#26
Akú àkókò yí ooo!
Inú mi dun láti rí wípé àyè wáà fún àwa omo yorùbá láti so èdè abínibí wa lóri forùmù yìí, ìdùnú ńlá lójé fúmi, mosì lérò pé aó fi ànfàní yìí dóòré pèlú ara wa, àti láti ran ra wa lówó lóri forùmù yí.

Osù méta séyìn ni mo darapò mó fórùmù yí, nkan ò rorùn ní ìbèrè, sùgbón mo dúpé lówó olóun pé mo ń tèsíwájú; mosì setán láti ní òré àti láti kó nípa bí ènìyàn selè se àseyorí lóri forùmù.
newbie
Activity: 131
Merit: 0
March 08, 2022, 03:14:54 PM
#25
Moki gbogbo omo yoruba towa ni forum yi Pata Pata, inu mi dun lati se awari forum ede yoruba. Pataki forum yini bi ati lese afani fun arawa gege bi omo yoruba. Ti eba wo awujo wa ni oni eripe owun orisi risi nkan losenle, ti eba wo country wa eri wipe ko si opportunities fun awa odo tori re lofiye ki aran arawa lowo. Bi abari update to le se afani fun awujo wa ki ama hesitate lati je ki awon egbe wa ma ni pare. Olorun ama tewa siwaju.
newbie
Activity: 9
Merit: 0
November 09, 2021, 04:21:20 AM
#24
Eyin temi bawo ni, adeku Orilede wa yin olorun ama bá denku orisirisi to selé ninu dié toku kì odun Eyin pari edumare awa pelu wa tebi tara.
legendary
Activity: 2716
Merit: 1225
Once a man, twice a child!
September 21, 2021, 09:00:44 PM
#23
I'm not Yoruba but two of the most important words which I heard most frequently during my brief stay in Kwara State, Oyo State and Ogun State and even among Yorubas in non-yoruba speaking states are:

1- eloni (how much?)
2- Soro Soke (speak up) - This one has an emotional undertone for me. We know why already.
And you didn't hear all the "Eku igbadu"? and "Eku Alejo"? That means you didn't flex while you were there then 😅
hero member
Activity: 1190
Merit: 901
Livecasino.io
September 17, 2021, 11:00:06 AM
#22
Mo ki gbogbo ile oooooo omoluabi a gbe wa ooooooooo oruko temi ni Nathrixxx ni forum apejopo was yi, inu mi dun pupo lati was laarin awon omo iya mi tooto, omo ilu Oyo ni ogbomoso ajilete ni bi ti nwan tin mu eko yangan Lori Amala to gbona felifeli, oruko ile baami ni ile abgoro ni eyin okeleerin adugbo aaje.


I'm not Yoruba but two of the most important words which I heard most frequently during my brief stay in Kwara State, Oyo State and Ogun State and even among Yorubas in non-yoruba speaking states are:

1- eloni (how much?)
2- Soro Soke (speak up) - This one has an emotional undertone for me. We know why already.
full member
Activity: 140
Merit: 128
September 08, 2021, 12:18:35 PM
#21
Mo ki gbogbo ile oooooo omoluabi a gbe wa ooooooooo oruko temi ni Nathrixxx ni forum apejopo was yi, inu mi dun pupo lati was laarin awon omo iya mi tooto, omo ilu Oyo ni ogbomoso ajilete ni bi ti nwan tin mu eko yangan Lori Amala to gbona felifeli, oruko ile baami ni ile abgoro ni eyin okeleerin adugbo aaje.
newbie
Activity: 25
Merit: 1
September 07, 2021, 02:15:25 PM
#20
Ekale ooooh Eyin temi bawo ni, inumidun pe MO wa nibi.
Ede yoruba ATI Asa yoruba MA gbe wa ooo
Ayewada koni baje fun wa
hero member
Activity: 1484
Merit: 928
August 08, 2021, 01:02:15 PM
#19
Oye ka le ma reran wa lowo pelu merit nibi. Lati ma ran our omo yoruba lowo lati ma sha awon ishe signature.
legendary
Activity: 1512
Merit: 4795
Leading Crypto Sports Betting & Casino Platform
May 10, 2021, 02:04:43 AM
#18
Inu mi dun lopo lopo wipe anfani wa fun wa lati so ede abi nibi wa ton se Yoruba. Aba kon soso ti moni ni wipe awon ara wa ti won ba ti wa loke ninu forumu Yi ni lati ran awa ti aba sese bere(newbie) lati de oke ninu forumu Yi. Aba mi o ju yelo
Otito ni wipe ede Yoruba o dara lopo lopo, sugbo a ni opo lopo lati se lati te si iwaji. A ni lati mo nipa bitcoin ati altcoin, ki awa lara awon ti o ma posti ni board gbogbogbo, nipa eyi, a ma te siwaju. O ma dara ki a wa si ibi lati ni ajoro ati lati beere ohun ti a ba mo nipa bi a se le lo bitcoin ati altcoin.
member
Activity: 154
Merit: 10
September 26, 2020, 11:00:16 AM
#17
Inu mi dun lopo lopo wipe anfani wa fun wa lati so ede abi nibi wa ton se Yoruba. Aba kon soso ti moni ni wipe awon ara wa ti won ba ti wa loke ninu forumu Yi ni lati ran awa ti aba sese bere(newbie) lati de oke ninu forumu Yi. Aba mi o ju yelo
jr. member
Activity: 462
Merit: 1
August 18, 2020, 05:41:48 PM
#16
Ẹ un' le nibi o
member
Activity: 91
Merit: 35
August 12, 2020, 02:03:36 PM
#15
Eku irole eyin omo oduduwa, inu mi dun lati rii wipe ede abininibi se patiki fun wa lopolopo. Olorun a tun bo ma gbe wa ga ninu gbogbo ohun ti a ba dawo le o. A ni so owo nu, ori buruku o ni je tiwa o. Amin.

Se enikeni mo ti aba ni ile ise crypto to gbajumo ni naijiria?
Pages:
Jump to: