Pages:
Author

Topic: Yoruba language - page 2. (Read 1017 times)

member
Activity: 127
Merit: 12
July 12, 2020, 05:19:15 PM
#14
Ede wa n dagba laisi idaduro, ati pe yoo ma tẹsiwaju lati dagbasoke.  ni awọn ọdun diẹ ti mbọ to o yoo mọ ni agbaye ati pe yoo kọ ọ ni diẹ ninu awọn aye miiran ti agbaye
newbie
Activity: 12
Merit: 3
July 06, 2020, 09:04:44 AM
#13
eyi jẹ ede lati ṣe agberaga fun. ṣugbọn bawo ni awa ọmọ Nigeria ti n ṣe igbega aaye aye crypto ni orilẹ-ede wa?
jr. member
Activity: 108
Merit: 1
June 17, 2020, 08:20:16 PM
#12
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
Kilo je "Waawu" nibiye? Shey nyi je ijile ede Yoruba ni? Mo ro kpe ede English niye.

 Grin Grin Otito ni oro ti e so...ede ayalo ni a le kaasi. Sugbon ju gbogbo re lo, mo dupe gidigidi l'owo yin fun bi e ti se fun mi ni merit ti mo beere fun. ko ni tan lowo yin o! Amin! Eseun leekan si
jr. member
Activity: 462
Merit: 1
June 01, 2020, 09:57:56 AM
#11
O wumi lati mọn nípa bi a sele tèsíwájú láti lè máa pa owó pẹlu kiriptokurensi. Inú mi yíò dun láti mọn awọn ọna daada na. Gbogbo wa lao se orire o. Amin
jr. member
Activity: 462
Merit: 1
June 01, 2020, 09:54:36 AM
#10
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
Kilo je "Waawu" nibiye? Shey nyi je ijile ede Yoruba ni? Mo ro kpe ede English niye.

Modúpé gidigidi fún meriti tí e fi dá mi Lola o.
Mon lóore o
legendary
Activity: 2716
Merit: 1225
Once a man, twice a child!
May 25, 2020, 12:00:06 AM
#9
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
Kilo je "Waawu" nibiye? Shey nyi je ijile ede Yoruba ni? Mo ro kpe ede English niye.
jr. member
Activity: 108
Merit: 1
May 16, 2020, 01:54:12 PM
#8
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
jr. member
Activity: 70
Merit: 5
April 06, 2020, 02:13:08 PM
#7
Eku dede asikoyi, Ara o le bi ? A de ku gbogbo rogbodiyan to shele ni agbalaye, ajalu buruku ko ni je ti gbogbo wa lola eledumare, eje ka tu bo tesiwaju nipa bi ase ma gbe asha wa laruge
jr. member
Activity: 462
Merit: 1
February 16, 2020, 04:33:30 PM
#6
Ekú deédé asìkò yi o.
Èmi jé IMO Bibi ipinle Òsun. Inú mi dun lato darapò mónyín níbí.
jr. member
Activity: 140
Merit: 2
December 09, 2019, 09:19:26 AM
#5
Nla lati wo intiative ti o jẹ ede abinibi ti orilẹ-ede Naijiria, Lọwọlọwọ ede Yoruba ni gbogbo agbaye sọ nitorinaa o yẹ ki o jẹ idanimọ, Mo nireti paṣipaarọ crypto laipe bi Huobi Global https://www.huobi.br.com/topic/invited/?invite_code=u8s64 yoo ni itumọ Yorùbá ti ipilẹ Syeed rẹ.
newbie
Activity: 74
Merit: 0
October 27, 2019, 08:02:17 PM
#4
Ede wa asa wa koni baje ooo
jr. member
Activity: 40
Merit: 1
FREE Cryptocurrency Decentralized Exchange
October 12, 2018, 05:32:57 AM
#3
E kaa ro sori eto awarawa  omobibi kaaro o ojiire.
Ejé ka jumô gbé isé yorùbá wa lárugê. Ê seun.
Samuel
member
Activity: 140
Merit: 10
November 12, 2017, 10:33:18 AM
#2
Inu mi dun lati je omo ibile yoruba...
Awa la ni asa awa naa lani owe...
Awa Yoruba lani arikose rere lara.
Eja ka fowo sowopo ka gbe asa wa laruge!...
newbie
Activity: 74
Merit: 0
November 04, 2017, 10:44:03 AM
#1
Asiko ni fun away omo Yoruba lati  ma so ede tiwa naa ni ibi gbogbo, ki ole ran ede wa lowo, papajulo ni gbogbo agbaye
Pages:
Jump to: